[VERSE 1]
Hello Sweety! Don’t cry; don’t cry;
wipe your tears
Awelewa, ma a worry; I go take you go OH
Pretty baby; don’t cry; big girls no dey cry (no dey cry)
Awelewa, ma a worry; you go follow me go
Bobo to fe e s’ile, se b’o se n se e ni yi o?
Eni l’ori o ni fila; se b’o se n t’oju e ni yi o?
[CHORUS]
Make I Fight For You; now, now, now;
Ololufe o (Je n jaa fun e o)
Ayaba ki n sun ‘kun (ahhh);
Ayaba ki n j’iya a (ahhhhh)
(Je n jaa fun e o)
You supposed dey happy (ahhh);
you supposed dey laugh o (ahhhhh)
(Je n jaa fun e o)
Je n jaa fun e o (ahhh); jaa fun e;
oh baby o (ahhhhh)
(Je n jaa fun e o)
[VERSE 2]
T’oba je Mike Tyson ni, mo ni size e l’owo
T’owo mi o ba ka, mo ni Bajinotu n’ile o
Bobo to fe e s’ile, se b’o se n se e ni yi o?
Eni l’ori o ni fila; se b’o se n t’oju e ni yi o?
[CHORUS]
Oleremi; make I Fight For You; now, now, now;
Ololufe o (Je n jaa fun e o)
Ayaba ki n sun ‘kun (ahhh);
Ayaba ki n j’iya a (ahhhhh)
(Je n jaa fun e o)
You supposed dey happy (ahhh);
you supposed dey laugh o (ahhhhh)
(Je n jaa fun e o)
Je n jaa fun e o (ahhh); jaa fun e;
oh baby o (ahhhhh)
(Je n jaa fun e o)
[VERSE 3- BRIDGE]
Ahh; ahhhh; ahhh; ahhhhh;
ah, ah, ah, ah, ah, ahhh
Make I Fight For You o;
o le f’eyin ti, f’eyin ti mi o
Awelewa; s’o gbo? (s’o gbo?; s’o gbo?; s’o gbo?)
Yeh; ohh; yeh, ehh; ohh
(oh, oh, oh, oh, ohhh)
Make I Fight For Youuu
(oh, oh, ohhhhhhhhh)
(Je n jaa fun e o) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
Awelewa (Ayaba, Ayabaa)
(Oh, oh, ohhhhhhhhh)
(Je n jaa fun e o) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
Make I; Make I Fight For You,
nah, nah, nah, nah; nahh (oh, ohhhh)
(Je n jaa fun e o) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
You supposed dey happy o; eh, eh, ehh
(Oohhhhhhhhh)
(Ayaba, Ayabaa) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
(Je n jaa fun e o) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
Awelewa, ahh; ahh; s’o gbo o? (Oohhhhhhhhh)
(Je n jaa fun e o) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)
(Oh, oh, oh, oh, ohhh) (Ayaba, Ayaba, Ayabaa)
(Oh, oh, ohhhhhhhhh)
(Je n jaa fun e o) (Oh, oh, ohhhhhhhhh)